Jobu 14:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìbá sàn kí o fi mí pamọ́ sinu ibojì,kí o pa mí mọ́ títí inú rẹ yóo fi rọ̀,ò bá dá àkókò fún mi, kí o sì ranti mi.

Jobu 14

Jobu 14:11-20