Jobu 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olè ń gbé ilé wọn ní alaafia,àwọn tí wọn ń mú Ọlọrun bínú wà ní àìléwu,àwọn tí ó jẹ́ pé agbára wọn ni Ọlọrun wọn.

Jobu 12

Jobu 12:2-10