Jobu 12:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ ti ní ìmọ̀, bẹ́ẹ̀ ni èmi náà ní,ẹ kò sàn jù mí lọ.Ta ni kò mọ irú nǹkan, tí ẹ̀ ń sọ yìí?

Jobu 12

Jobu 12:1-7