Jobu 12:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gba ìmọ̀ kúrò lọ́wọ́ àwọn ìjòyè ní gbogbo ayé,ó sì sọ wọ́n di alárìnká ninu aṣálẹ̀,níbi tí ọ̀nà kò sí.

Jobu 12

Jobu 12:18-25