Kì bá jẹ́ fi àṣírí ọgbọ́n hàn ọ́,nítorí ìmọ̀ rẹ̀ pọ̀ lọpọlọpọ.Mọ̀ dájú pé ìyà tí Ọlọrun fi jẹ ọ́kò to nǹkan lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.