Jobu 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹni ibi óo pòfo;gbogbo ọ̀nà tí wọ́n lè gbà sá àsálàni yóo parẹ́ mọ́ wọn lójú,ikú ni yóo sì jẹ́ ìrètí wọn.”

Jobu 11

Jobu 11:17-20