Jobu 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni o óo tó lè fi ìgboyà gbójú sókè láìlẹ́bi;o óo wà láìléwu,o kò sì ní bẹ̀rù.

Jobu 11

Jobu 11:6-20