Jobu 10:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ohun tí ó dára ni, Ọlọrunpé kí o máa ni eniyan lára,kí o kórìíra iṣẹ́ ọwọ́ rẹ,kí o sì fẹ́ràn ète ẹni ibi?

Jobu 10

Jobu 10:2-6