Jobu 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

O wá àwọn ẹlẹ́rìí tuntun pé kí wọ́n dojú kọ mí,O tún bẹ̀rẹ̀ sí bínú sí mi lọpọlọpọ,O mú kí ogun mìíràn dó tì mí.

Jobu 10

Jobu 10:14-20