Jobu 10:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo bá ṣe àìdára, mo gbé,ṣugbọn bí mo ṣe dáradára, n kò lè yangàn,nítorí ìbànújẹ́ ati ìtìjú bò mí mọ́lẹ̀.

Jobu 10

Jobu 10:6-19