Jobu 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bi Satani pé, “Níbo ni o ti ń bọ̀?”Satani dá OLUWA lóhùn pé, “Mò ń lọ sókè sódò káàkiri gbogbo ayé.”

Jobu 1

Jobu 1:1-14