Jobu 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Jobu bá dìde, ó fa aṣọ rẹ̀ ya láti fi ìbànújẹ́ rẹ̀ hàn; ó fá orí rẹ̀, ó dojúbolẹ̀, ó sì sin OLUWA.

Jobu 1

Jobu 1:15-22