Jeremaya 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ó ní:“Wò ó! N óo fọ̀ wọ́n mọ́,n óo dán wọn wò.Àbí, kí ni kí n tún ṣe fún àwọn eniyan yìí?

Jeremaya 9

Jeremaya 9:5-16