Jeremaya 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ikú ti dé ojú fèrèsé wa,ó ti wọ ààfin wa.Ikú ń pa àwọn ọmọde nígboro,ati àwọn ọdọmọkunrin ní gbàgede.”

Jeremaya 9

Jeremaya 9:13-22