Jeremaya 9:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìbá ṣe pé mo ní ilé èrò kan ninu aṣálẹ̀,ǹ bá kó àwọn eniyan mi dà sílẹ̀ níbẹ̀,ǹ bá sì kúrò lọ́dọ̀ wọn;nítorí alágbèrè ni gbogbo wọn,ati àgbájọ àwọn alárèékérekè eniyan.

Jeremaya 9

Jeremaya 9:1-3