Jeremaya 9:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí a gbọ́ tí ẹkún sọ ní Sioni,wọ́n ń ké pé, ‘A gbé!Ìtìjú ńlá dé bá wa,a níláti kó jáde nílé,nítorí pé àwọn ọ̀tá ti wó ilé wa.’ ”

Jeremaya 9

Jeremaya 9:16-26