Jeremaya 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní kí n sọ fún wọn pé,“Ṣé bí eniyan bá ṣubúkì í tún dìde mọ́?Àbí bí eniyan bá ṣìnà,kì í pada mọ́?

Jeremaya 8

Jeremaya 8:1-7