Jeremaya 8:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ọgbẹ́ àwọn eniyan mi ni ọkàn mi ṣe gbọgbẹ́.Mò ń ṣọ̀fọ̀, ìdààmú sì bá mi.

Jeremaya 8

Jeremaya 8:19-22