Jeremaya 8:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ ojú a tilẹ̀ máa tì wọ́nnígbà tí wọ́n bá ń hu ìwà ìbàjẹ́?Rárá o, ojú kì í tì wọ́n,nítorí pé wọn kò lójútì.Nítorí náà àwọn náà óo ṣubúnígbà tí àwọn yòókù bá ṣubú,a óo bì wọ́n ṣubúnígbà tí mo bá ń jẹ wọ́n níyà,OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.

Jeremaya 8

Jeremaya 8:4-19