Jeremaya 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀lé ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn yìí pé: “Tẹmpili OLUWA nìyí, kò séwu, tẹmpili OLUWA nìyí.”

Jeremaya 7

Jeremaya 7:1-13