Jeremaya 7:27 BIBELI MIMỌ (BM)

“Gbogbo ọ̀rọ̀ wọnyi ni o óo sọ fún wọn, ṣugbọn wọn kò ní gbọ́. O óo pè wọ́n, ṣugbọn wọn kò ní dá ọ lóhùn.

Jeremaya 7

Jeremaya 7:18-30