Jeremaya 7:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ọjọ́ tí àwọn baba ńlá yín ti jáde ní ilẹ̀ Ijipti títí di òní, lojoojumọ ni mò ń rán àwọn wolii iranṣẹ mi sí wọn léraléra.

Jeremaya 7

Jeremaya 7:23-34