Jeremaya 6:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má lọ sinu oko,ẹ má sì ṣe rìn lójú ọ̀nà náà,nítorí ọ̀tá mú idà lọ́wọ́,ìdágìrì sì wà káàkiri.

Jeremaya 6

Jeremaya 6:21-30