Jeremaya 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fi àwọn aṣọ́nà ṣọ́nà nítorí yín.Mo wí fún wọn pé,“Ẹ máa dẹtí sílẹ̀ sí fèrè ogun!”Ṣugbọn wọ́n ní, “A kò ní dẹtí sílẹ̀.”

Jeremaya 6

Jeremaya 6:7-20