Jeremaya 52:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá a sọ ọ̀rọ̀ rere, ó sì fi sí ipò tí ó ga jùlọ, àní ipò tí ó ga ju ti gbogbo àwọn ọba tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ ní Babiloni lọ.

Jeremaya 52

Jeremaya 52:22-33