Jeremaya 52:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ọba Babiloni mú Seraaya, olórí alufaa ati Sefanaya tí ó jẹ́ igbákejì rẹ̀ ati àwọn aṣọ́nà mẹtẹẹta.

Jeremaya 52

Jeremaya 52:21-34