Jeremaya 52:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ ogun Kalidea tí wọ́n wà pẹlu olórí àwọn tí ń ṣọ́ Nebukadinesari ọba wó gbogbo odi Jerusalẹmu lulẹ̀ patapata.

Jeremaya 52

Jeremaya 52:13-21