Jeremaya 52:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù karun-un, ní ọdún kọkandinlogun tí Nebukadinesari ọba Babiloni jọba, Nebusaradani, olórí àwọn tí ń ṣọ́ ọba Babiloni, wọ ìlú Jerusalẹmu.

Jeremaya 52

Jeremaya 52:8-21