Jeremaya 51:63 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya ní nígbà tí Seraaya bá ka ìwé yìí tán, kí ó di òkúta kan mọ́ ọn kí ó jù ú sí ààrin odò Yufurate,

Jeremaya 51

Jeremaya 51:58-64