Jeremaya 51:55 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí OLUWA ń wó Babiloni lulẹ̀,ó sì ń pa á lẹ́nu mọ́.Igbe wọn ta sókè bíi híhó omi òkun ńlá

Jeremaya 51

Jeremaya 51:47-56