Jeremaya 51:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Babiloni yóo sì di òkítì àlàpà, ati ibùgbé ajáko,yóo di ibi àríbẹ̀rù ati àrípòṣé, láìsí ẹnìkan kan ninu rẹ̀.

Jeremaya 51

Jeremaya 51:31-43