Jeremaya 51:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ti gba ibi ìsọdá odò,wọ́n ti dáná sun àwọn ibi ààbò,ìbẹ̀rùbojo sì ti mú àwọn ọmọ ogun.

Jeremaya 51

Jeremaya 51:22-40