Jeremaya 51:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun ti fi ara rẹ̀ búra,pé òun yóo mú kí àwọn eniyan kún inú rẹ bí eṣú,wọn yóo sì kígbe ìṣẹ́gun lé ọ lórí.

Jeremaya 51

Jeremaya 51:7-19