Jeremaya 51:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Wò ó! N óo gbé ẹ̀mí apanirun kan dìde sí Babiloni,ati sí àwọn ará Kalidea;

Jeremaya 51

Jeremaya 51:1-7