Jeremaya 50:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ sá kúrò láàrin Babiloni, ẹ jáde kúrò ní ilẹ̀ àwọn ará Kalidea, bí òbúkọ tí ó ṣáájú agbo ẹran.

Jeremaya 50

Jeremaya 50:1-18