Jeremaya 50:41 BIBELI MIMỌ (BM)

“Wò ó! Àwọn kan ń bọ̀ láti ìhà àríwá, orílẹ̀-èdè ńlá, ati ọpọlọpọ ọba,wọ́n ń gbára wọn jọ láti máa bọ̀ láti òkèèrè.

Jeremaya 50

Jeremaya 50:36-44