Jeremaya 50:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí àkókò bá tó, àwọn ọmọ Israẹli ati àwọn ọmọ Juda, yóo jọ wá pẹlu ẹkún, wọn yóo máa wá OLUWA Ọlọrun wọn.

Jeremaya 50

Jeremaya 50:2-12