Jeremaya 50:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbógun tì í ní gbogbo ọ̀nà,ẹ ṣí àká rẹ̀ sílẹ̀,ẹ kó o jọ bí òkítì ọkà,kí ẹ sì pa á run patapata,ẹ má dá ohunkohun sí ninu rẹ̀.

Jeremaya 50

Jeremaya 50:25-30