Jeremaya 50:20 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, Nígbà tí ó bá yá, tí àkókò bá tó, a óo wá ẹ̀ṣẹ̀ tì ní Israẹli ati Juda; nítorí pé n óo dáríjì àwọn tí mo bá ṣẹ́kù.”

Jeremaya 50

Jeremaya 50:19-28