Jeremaya 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé n kò wá ní jẹ wọ́n níyà fún àwọn nǹkan tí wọ́n ṣe wọnyi?Àbí n kò ní gbẹ̀san ara mi lára irú orílẹ̀-èdè yìí?

Jeremaya 5

Jeremaya 5:1-18