Jeremaya 5:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn eniyan burúkú wà láàrin àwọn eniyan mi,wọ́n ń dọdẹ eniyan bí ẹni dọdẹ ẹyẹ,wọ́n dẹ tàkúté, wọ́n fi ń mú eniyan.

Jeremaya 5

Jeremaya 5:18-27