Jeremaya 5:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wá gbọ́, ẹ̀yin òmùgọ̀, aláìlọ́gbọ́n,ẹ̀yin tí ẹ lójú, ṣugbọn tí ẹ kò ríran;ẹ létí, ṣugbọn tí ẹ kò gbọ́ràn.

Jeremaya 5

Jeremaya 5:14-29