Jeremaya 49:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Hasori yóo di ibùgbé ajáko,yóo di ahoro títí laelae.Ẹnìkan kò ní gbé ibẹ̀ mọ́,bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kò ní dé sibẹ mọ́.”

Jeremaya 49

Jeremaya 49:27-35