Jeremaya 48:46-47 BIBELI MIMỌ (BM)

46. Ẹ̀yin ará Moabu, ẹ gbé!Ó ti parí fun yín, ẹ̀yin ọmọ Kemoṣi,nítorí a ti kó àwọn ọmọkunrin yín lẹ́rú,a ti kó àwọn ọmọbinrin yín lọ sí ìgbèkùn.

47. “Sibẹsibẹ n óo dá ire Moabu pada lẹ́yìn ọ̀la,èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.Bẹ́ẹ̀ ni yóo rí fún Moabu.”

Jeremaya 48