Jeremaya 48:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun yóo kó àwọn ìlú Moabu,wọn óo sì gba àwọn ibi ààbò rẹ̀.Ní ọjọ́ náà, ọkàn àwọn ọmọ ogun Moabu yóo dàbí ọkàn obinrin tí ó ń rọbí,

Jeremaya 48

Jeremaya 48:35-45