Jeremaya 48:36 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà ni mo ṣe ń dárò Moabu ati àwọn ará Kiri Heresi bí ẹni fi fèrè kọ orin arò nítorí pé gbogbo ọrọ̀ tí wọ́n kó jọ ti ṣègbé.

Jeremaya 48

Jeremaya 48:33-40