Jeremaya 48:34 BIBELI MIMỌ (BM)

“Heṣiboni ati Eleale kígbe sókè, igbe wọn sì dé Jahasi láti Soari, ó dé Horonaimu ati Egilati Ṣeliṣiya. Àwọn odò Nimrimu pàápàá ti gbẹ.

Jeremaya 48

Jeremaya 48:30-35