Jeremaya 48:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ni mo ṣe ń sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, tí mò ń kígbe sókè nítorí Moabutí mo sì ń ṣọ̀fọ̀ nítorí àwọn ará Kiri Heresi.

Jeremaya 48

Jeremaya 48:25-34