Jeremaya 48:26 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Ẹ rọ Moabu lọ́tí yó,nítorí pé ó gbéraga sí OLUWA;kí ó lè máa yíràá ninu èébì rẹ̀,a óo sì fi òun náà ṣẹ̀sín.

Jeremaya 48

Jeremaya 48:18-32