Jeremaya 46:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ijipti ń ru bí odò Naili,bí odò tí ó kún bo bèbè rẹ̀.Ijipti wí pé, ‘N óo kún, n óo sì bo ayé mọ́lẹ̀,n óo pa àwọn ìlú ati àwọn tí wọn ń gbé inú wọn run.

Jeremaya 46

Jeremaya 46:6-18